Thursday, 6 April 2017

XBOSS FAN'S :WAEC 2017 Yoruba Expo

XBOSS FAN'S :WAEC 2017 Yoruba Expo
April 06, 2017
YORUBA QUESTIONS AND ANSWERS


YORUBA OBJ:
1ADDDBCDCAC
11DBCDCBCADC
21CDBCBABADD
31BBBCBBACAB
41DACDBBBDCB
51CDACAABCDD
(2a)
-[gb]:Konsonanti Akunyun Afafase-fete-pe
Asenupe
-[h]:Konsonanti Aikunyun Afitan-an na pe
Afunupe
-[k]:Konsonanti Aikunyun Afafase pe Asenupe
-[r]:Konsonanti Aikunyun Afafase pe Aferigipe
(2b)
[gb]:Bi apeere, ninu oro bi -igbin,agbagba,gbo
[h]:Bi apeere ninu oro bi-ehoro,iho, ahon
[k]:Bi apeere ninu bi-akaara,oka,katakata
[r]:Bi apeere ninu oro bi-Irin,irina
====================================


(4)
i) Oro oruko asebeere- oro oruko asebeere ni ama n fi ropo oro oruko miiran ninu gbolohun ibeere, bi apeere: Ewo
ii) Oro oruko asoye - oro oruko asoye maa n se idiwon bi oro oruko tio tele se po tokan-npe ni ki a fi eyan kun awon kan nigba ti awon kan je wofun Bi apeere - opolopo, ogunlogo
iii) Oro oruko afihan - oro oruko afihan ni a maa n seda eyan asefihan lati ara re Apeere - iyen - iwonyen Eyi - iwonyi
iv) Oro oruko ibikan - eyi je oro oruko ti maan lo 'ibo ' tabi ibikan se ibeere fun Bi apeere - ibadan, oyo, oba
V ) oro oruko igba - eyi ni oro oruko ti o maa n toka si igba /akoko ti nkan sele, ale fi igba wo se ibeere fun-unnBi apeere - won lo ni ana O gbera ni aro

5ai)
Gbolohun alaye
5aii)
Gbolohun ibeere
5aiii)
Gbolohun ase
5aiv)
Gbolohun amo
5av)
Gbolohun alalaye
5bi)
Ti o ba ri tunde,bami pe
5bii)
-
5biii)
Kani mori Tunde ni,mi o ni wa
5biv)
Yala ko losi Ilorin,tabi kowa si Ogbomoso
5bv)
Kaka ki n losi ileewe, ma lo si oko mi


Keep Refreshing this page.... .
 

 
Share This :
SUBSCRIBE TO OUR NEWSLETTER

Add Your Comments

bold <b>b</b>
italic <i>i</i>
underline <u>u</u>
HTML<code></code> use Parser

Emoticon
Parser
😊
😉
😀
😁
😎
😍
😜
😑
😇
💖
😯
😱
😭
👍
🍻